Verse 1:

Won ni mo ti ba ibo je
Ti emi o ba kalo te ika
Opo Oselu lon' se ika
Ohun la sen' tiraka
Ki a ma bale fi arapa
Ohun la sen' tan atupa
Won den' da wa la'raya
Awon ere ida raya
Ti awon Alagbada
Bi won tin'se ni Abuja
Won ni ki awa lo di ibo
Ki awon ba le ma ro ojo
Awa naa o de wa se ojo
Gbogbo wa ro lo di ibo
Amo bi ase di ibo tan'
Eye igun o wa ro ojo mo o
Opolo ti wo ori wa
Ni ipase awon ti oti lo o
Olaju ti wo ilu de eh
Mo ma di ibo legally

Chorus:

Ni igba ti kon'se Asasi
Mo ti wa fe ko enu si
Mi o den se omo Sanusi
Ki ema ni mo fi ako si
Awon kan ti gbe owo si
Ki won baa le ma l'owo si
Mekunu den'gboro si
Ki ema ni mose abosi
Awon eyan wa a to ja si
Ti awon agbaye ba da se
Abi se ofe ju ipo lo o
Melo ninu wa ni efe sin
Se alagbada la gbe si
Won tun'pon wa loju si
Olorun Orun ti o dami
Gbawa lo wo Bilisi

Chorus:

Ni ipa se awon Alagbara
Ohun la sen' sa Agbara
A o de le fi ra Akara
A kon'dun bi Sakara
Won wa ko wa ni Akala
Woni wipe aman'fa taba
Ni igba ti a o ba ri ona gba
Ibo la fe ri Akaba ah
Ki Ediye to le pa omo
Se lo koko ma saba ah
Omo ti ko ni Baba
Tani ko ba lo saba
Ounje ojo ko mo'ra
Oju 'nle bi ti ebora
Ti oba fe di Alagbara
Ko ya di ibo legally.

Chorus:

Shout out:
Correct  |  Mail  |  Print  |  Vote

ACCREDIT Lyrics

Morah – ACCREDIT Lyrics

More Morah lyrics