top 100
·
top new
·
updates
·
submit lyrics
#
A
B
C
D
E
F
G
H
I
J
K
L
M
N
O
P
Q
R
S
T
U
V
W
X
Y
Z
Correct ACCREDIT Lyrics
Lyrics
►
Artists: M
►
Morah
►
Correct ACCREDIT
Artist:
Song:
Comment:
Lyrics:
Verse 1: Won ni mo ti ba ibo je Ti emi o ba kalo te ika Opo Oselu lon' se ika Ohun la sen' tiraka Ki a ma bale fi arapa Ohun la sen' tan atupa Won den' da wa la'raya Awon ere ida raya Ti awon Alagbada Bi won tin'se ni Abuja Won ni ki awa lo di ibo Ki awon ba le ma ro ojo Awa naa o de wa se ojo Gbogbo wa ro lo di ibo Amo bi ase di ibo tan' Eye igun o wa ro ojo mo o Opolo ti wo ori wa Ni ipase awon ti oti lo o Olaju ti wo ilu de eh Mo ma di ibo legally Chorus: Ni igba ti kon'se Asasi Mo ti wa fe ko enu si Mi o den se omo Sanusi Ki ema ni mo fi ako si Awon kan ti gbe owo si Ki won baa le ma l'owo si Mekunu den'gboro si Ki ema ni mose abosi Awon eyan wa a to ja si Ti awon agbaye ba da se Abi se ofe ju ipo lo o Melo ninu wa ni efe sin Se alagbada la gbe si Won tun'pon wa loju si Olorun Orun ti o dami Gbawa lo wo Bilisi Chorus: Ni ipa se awon Alagbara Ohun la sen' sa Agbara A o de le fi ra Akara A kon'dun bi Sakara Won wa ko wa ni Akala Woni wipe aman'fa taba Ni igba ti a o ba ri ona gba Ibo la fe ri Akaba ah Ki Ediye to le pa omo Se lo koko ma saba ah Omo ti ko ni Baba Tani ko ba lo saba Ounje ojo ko mo'ra Oju 'nle bi ti ebora Ti oba fe di Alagbara Ko ya di ibo legally. Chorus: Shout out:
add rows