Ni gbogbo igba nba laju r’imole ojo
Mo ni ireti p’Oluwa ko jawo
Eni ti ku ko n’ireti Kankan
Emi wa laaye, Oluwa ko jawo
Ni gbogbo igba nba laju r’imole ojo
Mo ni ireti p’Oluwa ko jawo

Eni o mo ‘nu ro, ko ni s’ope
Oun Oluwa e se la maa saroye lori

O le ma saroye pe o bimo
O le ma saroye pe o k’ole
O le ma saroye pe o l’owo
O le ma saroye pe o seun ire

Eni ti ku ko nireti kankan
Eni wa laaye ni ileri Oluwa le se fun o
Eni wa laaye sini ireti

Gbo, bo ‘ku saju ogo
Eni to wa laye a lo ipo re

Ka to d’aye alaye nsaye
Ba o si mo o, alaye a saye

Ba o ku, ise o tan
Ba wa laye a j’eran to j’erin lo

Ka to d’aye alaye nsaye
Ba o si mo o, alaye a saye

Se jeje ko gb’aye o
Ma kanju w’ola
Duro d’asiko re

Ka to d’aye alaye nsaye
Ba o si mo o, alaye a saye

Bo ‘ku saju ogo
Eni to wa laye o ti lo ipo re tan pata

Ka to d’aye alaye nsaye
Ba o si mo o, alaye a saye
Ife t’Oluwa fe wa o
O ma po, o ma po

La fi wa laaye ati alafia ara

Aimoye eniyan loku
Aimoye eniyan ti s’ofo o

Ope f’Eduwa f’abo re
Ona mi a la peregede
Ire o Ire o Ire o awa mi ri
Ire o Ire o Ire o ko wa mi ri
Ire tete wa mi ri
Kenieleni ma gba ise mi se laye
Oju owo ma nrire ni
Koju mi ko rire, k’ire ba mi kale
Ire o Ire o Ire o ko wa mi ri
Baba tete wa f’oro mi se iyanu
Loju aroni pin kin le gbegba ope
Ire o Ire o Ire o a wa mi ri
Correct  |  Mail  |  Print  |  Vote

Mo Nireti Lyrics

Aryke – Mo Nireti Lyrics

More Aryke lyrics